Skip to main content

ETHNOS_APP

Home • Search • Journals • List 0

Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí

Bibliographic Data

ID22158955
AuthorsOlúyẹmisí Adébọ̀wálé (Adekunle Ajasin University), Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá (Adekunle Ajasin University)
Year2021
Volume6
Issue1
Pages1-17
Publication date2021-12-21
Open AccessYes
TypeARTICLE
VenueYoruba Studies Review (JOURNAL)
Journal identifiersISSN: 2473-4713 • E-ISSN: 2578-692X
PublisherUniversity of Florida George A Smathers Libraries (PUBLISHER)
DOI10.32473/ysr.v6i1.130088
OpenAlexW4206614899
LanguageVI
References cited1

Ògúnṣínà (1992), Adébọ̀wálé (1994) àti Ìṣọ̀lá (1995) ti ṣe àlàyé lórí ìlò èdè Òkédìjí nínú ìtàn-àròsọ Àjà Ló Lẹrù, Àgbàlagbà Akàn àti Ká Rìn Ká Pọ̀ ṣùgbọ́n kò sí lámèyítọ́ tó yẹ ìlò èébú wò nínú àwọn ìwé náà tàbí ti òǹkọ̀ wé ìtàn-àròsọ Yorùbá mìíràn. Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀ wò ìlò èébú nínú ìtàn-àròsọ Òkédìjí, ó sì lo ọgbọ́ n ìwádìí kíka àwọn ìwé náà ní àkàtúnkà láti ṣe àfàyọ àti àkójọpọ̀ gbogbo èébú tó súyọ kí a tó ṣe ìtúpalẹ̀ wọn. Tíọ́rì ọ̀nà ìṣafọ̀ tó jẹmọ́ èròǹgbà aṣafọ̀ àti ìmọ̀lára òsùnsùn-afọ̀ nípa afọ̀ la fi ṣe àlàyé wa. Ìgbà ọ̀ọ́dúnrún àti ọ̀kandínláàádọ́rùn-ún ni Òkédìjí ti lo èébú nínú àwọn ìtàn-àròsọ rẹ̀, ọ̀nà ìṣafọ̀ méjì tó gbà ṣe àgbékalẹ̀ èébú ni ìṣafọ̀ sínú àti ìṣafọ̀ síta. Ìsọ̀ rí èébú wọ̀ nyí lè jẹ́ èébú ti ẹlẹ́ yọ-ọ̀ rọ̀ , alápòólà, odindi gbólóhùn, oníbéèrè, òwe àti oríkì ajẹméèébú. Iṣẹ́ tí àwọn aṣafọ̀ fi èébú ṣe nínú ìsọ̀ rọ̀ gbèsì la fi kásẹ̀ àlàyé wa

Crystallography · Physics · Stereochemistry · Chemistry · Islamic Finance and Banking Studies · Language, Linguistics, Cultural Analysis · Linguistic, Cultural, and Literary Studies

  • A Dictionary of Linguistics and Phonetics

    David Crystal•Dictionary of Linguistics and…•2008

Highly citedNo

Tools

Open DOIOpen Access
Ethnos_APP • Open Source Project • MIT License • Frontend v2.0.0 • Privacy and Cookies • API Documentation: api.ethnos.app/docs • API Source Code: GitHub • DOI: 10.5281/zenodo.17049435 • Frontend Source Code: GitHub • DOI: 10.5281/zenodo.17050053 • cruz.rio.br • Expectantes Misericordiae