Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
Bibliographic Data
| ID | 22158969 |
|---|---|
| Authors | Abidemi Olusola Bolarinwa (0009-0007-2718-3870, University of Ibadan, corresponding author) |
| Year | 2021 |
| Volume | 6 |
| Issue | 1 |
| Pages | 1-19 |
| Publication date | 2021-12-21 |
| Open Access | Yes |
| Type | ARTICLE |
| Venue | Yoruba Studies Review (JOURNAL) |
| Journal identifiers | ISSN: 2473-4713 • E-ISSN: 2578-692X |
| Publisher | University of Florida George A Smathers Libraries (PUBLISHER) |
| DOI | 10.32473/ysr.v6i1.130098 |
| OpenAlex | W4206057971 |
| Language | VI |
| References cited | 5 |
Òkan pàtàkì lára lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá ni oríkì jẹ́, àwọn onímọ̀ lọ́kan- ̣ ò-jò kan ló sì ti wale ̣ ̀ jin lórí oríkì ṣùgbọ́n kò tí sí iṣẹ́ ìwádìí kan gbòógì tí ó ̣ jẹyọ lórí ìfarajọ-èébú nínú oríkì Yorùbá. Láti di àlàfo yìí, iṣẹ́ ìwádìí yìí fi tíọ́rì ìfìwádìí-sọ̀tumọ̀ ṣe àtẹ̀gùn láti ṣe àyẹ̀wò àwọn oríṣìí oríkì Yorùbá mẹ́ta tí ìfarajọ-èébú jẹyọ nínú wọn, èyí tí a ṣe àfàyọ wọ́n láti inú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tí a ṣe àti iṣẹ́ àpilẹ̀kọ àwọn onímọ̀. Àwọn oríkì náà ni oríkì orílẹ̀, oríkì àmútọ̀runwá àti oríkì ìlú. Ìwádìí yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé gbogbo àwọn ìpèdè tí ó farajọ èébú àti ìtìjú fún àwọn ènìyàn ní àwùjọ Yorùbá ni wó n kì í ṣe èébú ṣùgbọ́n tí wọ́n jẹ́ ̣ ohun àmúyangàn, ohun ọlá àti ẹ̀yẹ ní ìgbà tí a bá ti sọ ó di oríkì tí a sì fi ń ki ̣ àwọn olóríkì. Ohun ti èyí ń tọ́ka sí ni pé, àwọn àṣà àti èrò Yorùbá nípa èébú àti àbùkù máa ń yípadà ní ìgbà tí a bá ṣàmúlò wọn gẹ́gẹ́ bí oríkì ní ilẹ̀ Yorùbá, torí kì í ṣe èébú mọ́ ṣùgbọ́n ìtọ́ka sí ìtàn àti ìṣe akọni olóríkì ni
Physics · Chemistry · Creative Drama in Education · Japanese History and Culture · Legal Issues in Education
| Highly cited | No |
|---|